Orin Dafidi 136:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Òun nìkan ṣoṣo ní ń ṣe iṣẹ́ ìyanu ńlá,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

5. Ẹni tí ó fi ọgbọ́n dá ọ̀run,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae;

6. ẹni tí ó tẹ́ ilẹ̀ lé orí omi,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae;

Orin Dafidi 136