Orin Dafidi 136:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA tí ó ju gbogbo àwọn oluwa lọ,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

Orin Dafidi 136

Orin Dafidi 136:1-11