Orin Dafidi 135:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó rán iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu sí ilẹ̀ Ijipti,ó rán sí Farao ati gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀.

Orin Dafidi 135

Orin Dafidi 135:1-13