Orin Dafidi 135:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ló gbá ìkùukùu jọ láti òpin ilẹ̀ ayé,ó fi mànàmáná fún òjò,ó sì mú afẹ́fẹ́ jáde láti inú ilé ìṣúra rẹ̀.

Orin Dafidi 135

Orin Dafidi 135:1-16