Orin Dafidi 135:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ yin OLUWA, nítorí pé ó ṣeun;ẹ kọrin ìyìn sí i,nítorí pé olóore ọ̀fẹ́ ni.

Orin Dafidi 135

Orin Dafidi 135:1-4