Orin Dafidi 135:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA.Ẹ yin orúkọ OLUWA;ẹ yìn ín, ẹ̀yin iranṣẹ rẹ̀,

2. ẹ̀yin tí ẹ̀ ń jọ́sìn ninu ilé OLUWA,tí ẹ wà ní àgbàlá ilé Ọlọrun wa.

Orin Dafidi 135