Orin Dafidi 131:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ ní ìrètí ninu OLUWA,láti ìsinsìnyìí lọ ati títí laelae.

Orin Dafidi 131

Orin Dafidi 131:1-3