OLUWA, n kò ṣe ìgbéraga,bẹ́ẹ̀ ni ojú mi kò gbé sókè.N ò dáwọ́ lé nǹkan ńláńlá,n ò sì dá àrà tí ó jù mí lọ.