Orin Dafidi 129:7-8 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Kò lè kún ọwọ́ ẹni tí ń pa koríko;kò sì lè kún ọwọ́ ẹni tí ń di koríko ní ìtí.

8. Àwọn èrò ọ̀nà kò sì ní kí ẹni tí ń gé e pé:“OLUWA óo fèrè síṣẹ́ o!Ẹ kúuṣẹ́, OLUWA óo fèrè sí i.”

Orin Dafidi 129