Orin Dafidi 126:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rẹ̀kẹ́ wa kún fún ẹ̀rín, a sì kọrin ayọ̀,nígbà náà ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù ń wí pé,“OLUWA mà ṣe nǹkan ńlá fún àwọn eniyan yìí!”

Orin Dafidi 126

Orin Dafidi 126:1-6