Orin Dafidi 124:7-8 BIBELI MIMỌ (BM)

7. A ti yọ, bí ẹyẹ tí ó yọ ninu okùn apẹyẹ:okùn ti já; àwa sì ti yọ.

8. Ọ̀dọ̀ OLUWA ni ìrànlọ́wọ́ wa ti wá,ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé.

Orin Dafidi 124