Orin Dafidi 124:5-8 BIBELI MIMỌ (BM)

5. ìgbì omi ìbá ti gbé wa mì.”

6. Ọpẹ́ ni fún OLUWA,tí kò fi wá ṣe ẹran ìjẹ fún wọn.

7. A ti yọ, bí ẹyẹ tí ó yọ ninu okùn apẹyẹ:okùn ti já; àwa sì ti yọ.

8. Ọ̀dọ̀ OLUWA ni ìrànlọ́wọ́ wa ti wá,ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé.

Orin Dafidi 124