Orin Dafidi 124:2-5 BIBELI MIMỌ (BM)

2. “Tí kì í bá ṣe pé OLUWA tí ó wà lẹ́yìn wanígbà tí ọmọ aráyé gbógun tì wá,

3. wọn ìbá gbé wa mì láàyè,nígbà tí inú bí wọn sí wa;

4. àgbàrá ìbá ti gbá wa lọ,ìṣàn omi ìbá ti bò wá mọ́lẹ̀;

5. ìgbì omi ìbá ti gbé wa mì.”

Orin Dafidi 124