Orin Dafidi 122:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Inú mi dùn nígbà tí wọ́n wí fún mi pé,“Ẹ jẹ́ kí á lọ sí ilé OLUWA.”

2. A ti tẹsẹ̀ bọ inú ìgboro rẹ, Jerusalẹmu.

3. Jerusalẹmu, ìlú ńlá tí a kọ́,tí gbogbo rẹ̀ já pọ̀ di ọ̀kan.

Orin Dafidi 122