Orin Dafidi 121:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ ó yẹ̀,ẹni tí ń pa ọ́ mọ́ kò ní tòògbé.

Orin Dafidi 121

Orin Dafidi 121:1-8