Orin Dafidi 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí pé, “Nítorí ìnira àwọn aláìṣẹ̀,ati nítorí ìkérora àwọn tí à ń pọ́n lójú,n óo dìde nisinsinyii,n óo sì dáàbò bò wọ́n bí ọkàn wọn ti ń fẹ́.”

Orin Dafidi 12

Orin Dafidi 12:1-8