Orin Dafidi 119:99 BIBELI MIMỌ (BM)

Òye mi ju ti àwọn olùkọ́ mi lọ,nítorí pé ìlànà rẹ ni mo fi ń ṣe àṣàrò.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:93-109