Orin Dafidi 119:78 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ojú ó ti àwọn onigbeeraga,nítorí wọ́n ṣe àrékérekè sí mi láìnídìí;ní tèmi, n óo máa ṣe àṣàrò lórí òfin rẹ.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:74-87