Orin Dafidi 119:7 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo yìn ọ́ pẹlu inú mímọ́,bí mo ṣe ń kọ́ ìlànà òdodo rẹ.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:1-11