Orin Dafidi 119:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bọ̀wọ̀ fún àṣẹ rẹ tí mo fẹ́ràn,n óo sì máa ṣe àṣàrò lórí ìlànà rẹ.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:44-58