Orin Dafidi 119:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn ìjòyè tilẹ̀ gbìmọ̀ràn ọ̀tẹ̀ nítorí mi,sibẹ, èmi iranṣẹ rẹ yóo ṣe àṣàrò lórí ìlànà rẹ.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:20-30