Orin Dafidi 119:159 BIBELI MIMỌ (BM)

Wo bí mo ti fẹ́ ẹ̀kọ́ rẹ tó!Dá mi sí gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:149-169