Orin Dafidi 119:133 BIBELI MIMỌ (BM)

Mú ẹsẹ̀ mi dúró gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ,má sì jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ kankan jọba lórí mi.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:131-134