Orin Dafidi 119:123 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fojú sọ́nà títí, agara dá mi,níbi tí mo tí ń retí ìgbàlà rẹ,ati ìmúṣẹ ìlérí òdodo rẹ.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:113-125