Orin Dafidi 119:118 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti kọ gbogbo àwọn tí ó yapa kúrò ninu ìlànà rẹ sílẹ̀,nítorí pé asán ni gbogbo ẹ̀tàn wọn.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:115-119