Orin Dafidi 118:27 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ni Ọlọrun, ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí wa.Pẹlu ẹ̀ka igi lọ́wọ́, ẹ bẹ̀rẹ̀ ayẹyẹ ìwọ́de ẹbọ náà,títí dé ibi ìwo pẹpẹ.

Orin Dafidi 118

Orin Dafidi 118:23-29