Orin Dafidi 118:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́ orin ayọ̀ ìṣẹ́gun,ninu àgọ́ àwọn olódodo.“Ọwọ́ ọ̀tún OLUWA ti ṣe iṣẹ́ agbára ńlá.

Orin Dafidi 118

Orin Dafidi 118:10-17