Orin Dafidi 116:18-19 BIBELI MIMỌ (BM)

18. N óo san ẹ̀jẹ́ mi fún OLUWAlójú gbogbo àwọn eniyan rẹ̀,

19. ninu àgbàlá ilé OLUWA,láàrin rẹ, ìwọ ìlú Jerusalẹmu.Ẹ máa yin OLUWA!

Orin Dafidi 116