Orin Dafidi 115:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. OLUWA ló ni ọ̀run,ṣugbọn ó fi ayé fún àwọn eniyan.

17. Àwọn òkú kò lè yin OLUWA,àní àwọn tí wọ́n ti dákẹ́ ninu ibojì.

18. Ṣugbọn àwa yóo máa yin OLUWA,láti ìsinsìnyìí lọ, ati títí laelae.Ẹ máa yin OLUWA.

Orin Dafidi 115