Orin Dafidi 115:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ògo kì í ṣe fún wa, OLUWA, Kì í ṣe fún wa,orúkọ rẹ nìkan ṣoṣo ni kí á yìn lógo,nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ati nítorí òtítọ́ rẹ.

Orin Dafidi 115

Orin Dafidi 115:1-10