Orin Dafidi 113:8-9 BIBELI MIMỌ (BM)

8. láti mú wọn jókòó láàrin àwọn ìjòyè,àní, àwọn ìjòyè àwọn eniyan rẹ̀.

9. Ó sọ àgàn di ọlọ́mọ,ó sọ ọ́ di abiyamọ onínúdídùn.Ẹ máa yin OLUWA.

Orin Dafidi 113