Orin Dafidi 113:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA!Ẹ yìn ín, ẹ̀yin iranṣẹ OLUWA.Ẹ yin orúkọ OLUWA.

2. Kí á yin orúkọ OLUWA,láti ìsinsìnyìí lọ títí laelae.

Orin Dafidi 113