Orin Dafidi 112:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo máa dára fún ẹni tí ó bá lójú àánú, tí ó sì ń yáni ní nǹkan,tí ó ń ṣe ẹ̀tọ́ ní gbogbo ọ̀nà.

Orin Dafidi 112

Orin Dafidi 112:1-10