Orin Dafidi 111:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ yin OLUWA!N óo dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA tọkàntọkàn,láàrin àwọn olódodo,ati ní àwùjọ àwọn eniyan.

Orin Dafidi 111

Orin Dafidi 111:1-10