Orin Dafidi 110:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan rẹ yóo fi tọkàntọkàn fa ara wọn kalẹ̀,lọ́jọ́ tí o bá ń kó àwọn ọmọ ogun rẹ jọ lórí òkè mímọ́.Àwọn ọ̀dọ́ yóo jáde tọ̀ ọ́ wá bí ìrì òwúrọ̀.

Orin Dafidi 110

Orin Dafidi 110:1-7