Orin Dafidi 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí olódodo ni OLUWA, ó sì fẹ́ràn òdodo;àwọn olóòótọ́ ni yóo rí ojú rẹ̀.

Orin Dafidi 11

Orin Dafidi 11:1-7