Orin Dafidi 109:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí a bá ń dá ẹjọ́ rẹ̀,jẹ́ kí wọn dá a lẹ́bi;kí ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ di ọ̀ràn sí i lọ́rùn.

Orin Dafidi 109

Orin Dafidi 109:1-8