Orin Dafidi 109:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi fẹ́ràn wọn; ṣugbọn ẹ̀sùn ni wọ́n fi ń kàn mí,sibẹ, adura ni mò ń gbà fún wọn.

Orin Dafidi 109

Orin Dafidi 109:3-6