Orin Dafidi 109:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí wọn máa ṣépè, ṣugbọn kí ìwọ máa súre.Kí ojú ti àwọn alátakò mi,kí inú èmi, iranṣẹ rẹ, sì máa dùn.

Orin Dafidi 109

Orin Dafidi 109:22-31