Orin Dafidi 109:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fẹ́ràn láti máa ṣépè;nítorí náà kí èpè rẹ̀ dà lé e lórí;inú rẹ̀ kò dùn sí ìre,nítorí náà kí ìre jìnnà sí i.

Orin Dafidi 109

Orin Dafidi 109:13-19