Orin Dafidi 109:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn ọmọ rẹ̀ di alárìnká,kí wọn máa ṣagbe kiri;kí á lé wọn jáde kúrò ninu ahoro tí wọn ń gbé.

Orin Dafidi 109

Orin Dafidi 109:3-14