8. Tèmi ni Gileadi, tèmi sì ni Manase.Efuraimu ni àkẹtẹ̀ àṣíborí mi,Juda sì ni ọ̀pá àṣẹ mi.
9. Moabu ni ìkòkò ìwẹsẹ̀ mi,lórí Edomu ni n óo bọ́ bàtà mi lé,n óo sì hó ìhó ìṣẹ́gun lórí Filistia.”
10. Ta ni yóo mú mi wọ inú ìlú olódi náà?Ta ni yóo mú mi lọ sí Edomu?