Orin Dafidi 108:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ti sọ̀rọ̀ ninu ilé mímọ́ rẹ̀,ó ní, “Tayọ̀tayọ̀ ni n óo fi pín Ṣekemu,n óo sì pín àfonífojì Sukotu.

Orin Dafidi 108

Orin Dafidi 108:1-13