Orin Dafidi 107:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí wọn máa yin OLUWA nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,àní nítorí àwọn iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe fún àwọn ọmọ eniyan.

Orin Dafidi 107

Orin Dafidi 107:1-12