Orin Dafidi 107:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí yọ̀ nígbà tí ilẹ̀ rọ̀,ó sì mú kí wọ́n gúnlẹ̀ sí èbúté ìfẹ́ wọn.

Orin Dafidi 107

Orin Dafidi 107:23-36