Orin Dafidi 107:3 BIBELI MIMỌ (BM)

tí ó kó wọn jáde kúrò láàrin àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀n-ọn-nì,láti ìhà ìlà oòrùn ati láti ìhà ìwọ̀ oòrùn,láti ìhà àríwá ati láti ìhà gúsù.

Orin Dafidi 107

Orin Dafidi 107:2-9