Orin Dafidi 107:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkọ̀ ojú omi fò sókè roro,wọ́n sì tún já wá sílẹ̀ dòò, sinu ibú,jìnnìjìnnì bò wọ́n ninu ewu tí wọ́n wà.

Orin Dafidi 107

Orin Dafidi 107:24-32