Orin Dafidi 107:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí wọn máa yin OLUWA nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,àní, nítorí àwọn iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe fún eniyan.

Orin Dafidi 107

Orin Dafidi 107:20-31