Orin Dafidi 107:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí wọn máa yin OLUWA nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,àní nítorí àwọn iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe fún eniyan.

Orin Dafidi 107

Orin Dafidi 107:13-17