Orin Dafidi 106:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí n lè rí ire àwọn àyànfẹ́ rẹkí n lè ní ìpín ninu ayọ̀ àwọn eniyan rẹ,kí n sì lè máa ṣògo pẹlu àwọn tí ó jẹ́ eniyan ìní rẹ.

Orin Dafidi 106

Orin Dafidi 106:1-11